2 Àwọn Ọba 25:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó dáná sun ilé Jèhófà+ àti ilé* ọba+ pẹ̀lú gbogbo ilé tó wà ní Jerúsálẹ́mù;+ ó tún sun ilé gbogbo àwọn ẹni ńlá.+ 10 Gbogbo ògiri tó yí Jerúsálẹ́mù ká ni gbogbo àwọn ọmọ ogun Kálídíà tó wà pẹ̀lú olórí ẹ̀ṣọ́ wó lulẹ̀.+ Jeremáyà 39:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ìgbà náà ni àwọn ará Kálídíà dáná sun ilé* ọba àti ilé àwọn èèyàn náà,+ wọ́n sì wó àwọn odi Jerúsálẹ́mù lulẹ̀.+
9 Ó dáná sun ilé Jèhófà+ àti ilé* ọba+ pẹ̀lú gbogbo ilé tó wà ní Jerúsálẹ́mù;+ ó tún sun ilé gbogbo àwọn ẹni ńlá.+ 10 Gbogbo ògiri tó yí Jerúsálẹ́mù ká ni gbogbo àwọn ọmọ ogun Kálídíà tó wà pẹ̀lú olórí ẹ̀ṣọ́ wó lulẹ̀.+
8 Ìgbà náà ni àwọn ará Kálídíà dáná sun ilé* ọba àti ilé àwọn èèyàn náà,+ wọ́n sì wó àwọn odi Jerúsálẹ́mù lulẹ̀.+