Jeremáyà 11:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ẹni tó gbìn ọ́,+ ti kéde pé àjálù yóò bá ọ nítorí ìwà ibi tí ilé Ísírẹ́lì àti ilé Júdà hù, tí wọ́n ń mú mi bínú bí wọ́n ṣe ń rú ẹbọ sí Báálì.”+
17 “Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ẹni tó gbìn ọ́,+ ti kéde pé àjálù yóò bá ọ nítorí ìwà ibi tí ilé Ísírẹ́lì àti ilé Júdà hù, tí wọ́n ń mú mi bínú bí wọ́n ṣe ń rú ẹbọ sí Báálì.”+