Jeremáyà 44:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àwọn obìnrin náà sọ pé: “Nígbà tí à ń rú ẹbọ sí Ọbabìnrin Ọ̀run,* tí a sì ń da ọrẹ ohun mímu jáde sí i, ṣebí àwọn ọkọ wa lọ́wọ́ sí i pé kí a máa ṣe àkàrà ìrúbọ ní ìrísí rẹ̀, kí a sì máa da ọrẹ ohun mímu jáde sí i?”
19 Àwọn obìnrin náà sọ pé: “Nígbà tí à ń rú ẹbọ sí Ọbabìnrin Ọ̀run,* tí a sì ń da ọrẹ ohun mímu jáde sí i, ṣebí àwọn ọkọ wa lọ́wọ́ sí i pé kí a máa ṣe àkàrà ìrúbọ ní ìrísí rẹ̀, kí a sì máa da ọrẹ ohun mímu jáde sí i?”