-
Jeremáyà 44:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Kàkà bẹ́ẹ̀, a ó rí i dájú pé a ṣe gbogbo ohun tó ti ẹnu wa jáde, láti rú ẹbọ sí Ọbabìnrin Ọ̀run* àti láti da ọrẹ ohun mímu jáde sí i,+ bí àwa àti àwọn baba ńlá wa, àwọn ọba wa àti àwọn ìjòyè wa ti ṣe ní àwọn ìlú Júdà àti ní àwọn ojú ọ̀nà Jerúsálẹ́mù, nígbà tí a máa ń jẹ oúnjẹ ní àjẹtẹ́rùn, tí nǹkan sì ń dáa fún wa, tí a kò sì rí àjálù kankan.
-