-
Jeremáyà 25:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Nítorí ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ fún mi nìyí: “Gba ife wáìnì ìbínú yìí ní ọwọ́ mi, kí o sì mú kí gbogbo orílẹ̀-èdè tí mo bá rán ọ sí mu ún.
-
-
Ìsíkíẹ́lì 29:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 “Ọmọ èèyàn, yíjú sọ́dọ̀ Fáráò ọba Íjíbítì, kí o sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí rẹ̀ àti sórí gbogbo Íjíbítì.+
-