-
Ìsíkíẹ́lì 30:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 “Ọmọ èèyàn, mo ti kán apá Fáráò ọba Íjíbítì; wọn ò ní dì í kó lè jinná tàbí kí wọ́n fi aṣọ wé e kó lè lágbára tó láti di idà mú.”
-