Ìsíkíẹ́lì 29:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Sọ pé: ‘Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Èmi yóò bá ọ jà, ìwọ Fáráò ọba Íjíbítì,+Ẹran ńlá inú àwọn odò Náílì* rẹ̀,+Tó sọ pé, ‘Èmi ni mo ni odò Náílì mi. Ara mi ni mo ṣe é fún.’+
3 Sọ pé: ‘Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Èmi yóò bá ọ jà, ìwọ Fáráò ọba Íjíbítì,+Ẹran ńlá inú àwọn odò Náílì* rẹ̀,+Tó sọ pé, ‘Èmi ni mo ni odò Náílì mi. Ara mi ni mo ṣe é fún.’+