1 Àwọn Ọba 18:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Torí náà, Áhábù gòkè lọ kí ó lè jẹ, kí ó sì mu, àmọ́ Èlíjà lọ sí orí Òkè Kámẹ́lì, ó bẹ̀rẹ̀ mọ́lẹ̀, ó sì gbé orí rẹ̀ sáàárín eékún rẹ̀.+
42 Torí náà, Áhábù gòkè lọ kí ó lè jẹ, kí ó sì mu, àmọ́ Èlíjà lọ sí orí Òkè Kámẹ́lì, ó bẹ̀rẹ̀ mọ́lẹ̀, ó sì gbé orí rẹ̀ sáàárín eékún rẹ̀.+