Náhúmù 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ṣé o sàn ju No-ámónì* lọ,+ tó jókòó sí ẹ̀gbẹ́ ipa odò Náílì?+ Omi ló yí i ká;Òkun ni ọrọ̀ rẹ̀, òkun sì ni ògiri rẹ̀.
8 Ṣé o sàn ju No-ámónì* lọ,+ tó jókòó sí ẹ̀gbẹ́ ipa odò Náílì?+ Omi ló yí i ká;Òkun ni ọrọ̀ rẹ̀, òkun sì ni ògiri rẹ̀.