Ìsíkíẹ́lì 30:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Màá pa Pátírọ́sì+ run, màá dá iná sí Sóánì, màá sì dá Nóò* lẹ́jọ́.+