-
Sefanáyà 2:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 “Ẹ gbé! Ẹ̀yin tó ń gbé etí òkun, orílẹ̀-èdè àwọn Kérétì.+
Jèhófà ti bá yín wí.
Ìwọ Kénáánì, ilẹ̀ àwọn Filísínì, màá pa ọ́ run,
Tí kò fi ní sí olùgbé kan tó máa ṣẹ́ kù.
-