Sáàmù 24:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ta ni Ọba ológo yìí? Jèhófà ni, ẹni tó ní okun àti agbára,+Jèhófà, akin lójú ogun.+