ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 3:24, 25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Nígbà tí wọ́n wọ ibùdó Ísírẹ́lì, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dìde, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í pa àwọn ọmọ Móábù, tí wọ́n fi sá kúrò níwájú wọn.+ Wọ́n wọ inú Móábù, wọ́n sì ń pa àwọn ọmọ Móábù bí wọ́n ṣe ń lọ. 25 Wọ́n wó ìlú náà palẹ̀, àwọn ọkùnrin náà lọ́kọ̀ọ̀kan sì ju òkúta sórí gbogbo ilẹ̀ tó dára, títí òkúta fi kún gbogbo ilẹ̀ náà; wọ́n dí gbogbo orísun omi pa,+ wọ́n sì gé gbogbo igi tó dára lulẹ̀.+ Níkẹyìn, àwọn ògiri olókùúta Kiri-hárésétì+ nìkan ló ṣẹ́ kù ní ìdúró, àwọn tó ń ta kànnàkànnà yí i ká, wọ́n sì wó o lulẹ̀.

  • Àìsáyà 16:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Torí náà, Móábù máa pohùn réré ẹkún torí Móábù;

      Gbogbo wọn máa pohùn réré ẹkún.+

      Àwọn tí wọ́n lù máa dárò torí ìṣù àjàrà gbígbẹ ti Kiri-hárésétì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́