Léfítíkù 19:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ kọ ara yín lábẹ torí ẹni tó kú,*+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ fín àmì sí ara yín. Èmi ni Jèhófà.