-
Jeremáyà 48:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 “A ti gbọ́ nípa ìgbéraga Móábù, ó gbéra ga gan-an,
Nípa ìjọra-ẹni-lójú rẹ̀, ìgbéraga rẹ̀, ìṣefọ́nńté rẹ̀ àti nípa ọkàn gíga rẹ̀.”+
-