-
Nọ́ńbà 21:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Torí Hẹ́ṣíbónì ni ìlú Síhónì ọba àwọn Ámórì, ẹni tó bá ọba Móábù jà, tó sì gba gbogbo ilẹ̀ rẹ̀ lọ́wọ́ rẹ̀ títí lọ dé Áánónì.
-
-
Nọ́ńbà 21:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Torí iná jáde wá láti Hẹ́ṣíbónì, ọwọ́ iná láti ìlú Síhónì.
Ó ti jó Árì ti Móábù run, àwọn olúwa àwọn ibi gíga Áánónì.
-