ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 36:10, 11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Orúkọ àwọn ọmọkùnrin Ísọ̀ nìyí: Élífásì ọmọ Ádà ìyàwó Ísọ̀; Réúẹ́lì ọmọ Básémátì ìyàwó Ísọ̀.+

      11 Àwọn ọmọ Élífásì ni Témánì,+ Ómárì, Séfò, Gátámù àti Kénásì.+

  • Ìsíkíẹ́lì 25:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Màá tún na ọwọ́ mi láti fìyà jẹ Édómù, èmi yóò pa àwọn èèyàn àti ẹran ọ̀sìn ibẹ̀, èmi yóò sì sọ ọ́ di ahoro.+ Idà ni yóò pa wọ́n láti Témánì títí dé Dédánì.+

  • Émọ́sì 1:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Torí náà, màá rán iná sí Témánì,+

      Á sì jó àwọn ilé gogoro tó láàbò ti Bósírà run.’+

  • Ọbadáyà 8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ní ọjọ́ yẹn,” ni Jèhófà wí,

      “Èmi yóò pa àwọn ọlọ́gbọ́n run kúrò ní Édómù+

      Èmi yóò sì pa òye run ní agbègbè olókè Ísọ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́