Jeremáyà 49:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Nítorí mo ti fi ara mi búra,” ni Jèhófà wí, “pé Bósírà á di ohun àríbẹ̀rù,+ ohun ẹ̀gàn, ibi ìparun àti ègún; gbogbo àwọn ìlú rẹ̀ á sì di àwókù títí láé.”+
13 “Nítorí mo ti fi ara mi búra,” ni Jèhófà wí, “pé Bósírà á di ohun àríbẹ̀rù,+ ohun ẹ̀gàn, ibi ìparun àti ègún; gbogbo àwọn ìlú rẹ̀ á sì di àwókù títí láé.”+