Jeremáyà 9:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Màá sunkún, màá sì kédàárò nítorí àwọn òkèMàá sì kọ orin arò* nítorí àwọn ibi ìjẹko tó wà ní aginjù,Torí a ti dáná sun wọ́n kí ẹnì kankan má bàa gba ibẹ̀ kọjá,A ò gbọ́ ìró ẹran ọ̀sìn níbẹ̀ mọ́. Àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run àti ẹranko ti sá, gbogbo wọn ti lọ.+
10 Màá sunkún, màá sì kédàárò nítorí àwọn òkèMàá sì kọ orin arò* nítorí àwọn ibi ìjẹko tó wà ní aginjù,Torí a ti dáná sun wọ́n kí ẹnì kankan má bàa gba ibẹ̀ kọjá,A ò gbọ́ ìró ẹran ọ̀sìn níbẹ̀ mọ́. Àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run àti ẹranko ti sá, gbogbo wọn ti lọ.+