Àìsáyà 13:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ọfà wọn máa run àwọn ọ̀dọ́kùnrin túútúú;+Wọn ò ní káàánú èso ikùn,Wọn ò sì ní ṣàánú àwọn ọmọdé. Jeremáyà 51:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Ẹ dán ọfà;+ ẹ gbé àwọn apata ribiti.* Jèhófà ti ru ẹ̀mí àwọn ọba Mídíà sókè,+Torí ó ní in lọ́kàn láti pa Bábílónì run. Nítorí ẹ̀san Jèhófà nìyí, ẹ̀san nítorí tẹ́ńpìlì rẹ̀.
11 “Ẹ dán ọfà;+ ẹ gbé àwọn apata ribiti.* Jèhófà ti ru ẹ̀mí àwọn ọba Mídíà sókè,+Torí ó ní in lọ́kàn láti pa Bábílónì run. Nítorí ẹ̀san Jèhófà nìyí, ẹ̀san nítorí tẹ́ńpìlì rẹ̀.