-
Jeremáyà 51:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Màá fi ọ́ fọ́ olùṣọ́ àgùntàn àti agbo ẹran rẹ̀ túútúú.
Màá fi ọ́ fọ́ àgbẹ̀ àti àwọn ẹran ìtúlẹ̀ rẹ̀ túútúú.
Màá fi ọ́ fọ́ àwọn gómìnà àti àwọn ìjòyè túútúú.
-