-
Jeremáyà 51:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 “Àwọn èèyàn kò ní mú òkúta igun ilé tàbí òkúta ìpìlẹ̀ nínú rẹ,
Nítorí pé wàá di ahoro títí láé,”+ ni Jèhófà wí.