Àìsáyà 47:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Ẹni tó ń tún wa rà,Ni Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,+Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀.”