Àìsáyà 13:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Bábílónì tó lógo* jù nínú àwọn ìjọba,+Ẹwà àti ògo àwọn ará Kálídíà,+Máa dà bíi Sódómù àti Gòmórà nígbà tí Ọlọ́run bì wọ́n ṣubú.+
19 Bábílónì tó lógo* jù nínú àwọn ìjọba,+Ẹwà àti ògo àwọn ará Kálídíà,+Máa dà bíi Sódómù àti Gòmórà nígbà tí Ọlọ́run bì wọ́n ṣubú.+