Àìsáyà 13:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Wọ́n ń bọ̀ láti ilẹ̀ tó jìnnà,+Láti ìkángun ọ̀run,Jèhófà àti àwọn ohun ìjà ìbínú rẹ̀,Láti pa gbogbo ayé run.+ Àìsáyà 13:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Màá gbé àwọn ará Mídíà dìde sí wọn,+Àwọn tí kò ka fàdákà sí nǹkan kan,Tí wúrà ò sì já mọ́ nǹkan kan lójú wọn.
5 Wọ́n ń bọ̀ láti ilẹ̀ tó jìnnà,+Láti ìkángun ọ̀run,Jèhófà àti àwọn ohun ìjà ìbínú rẹ̀,Láti pa gbogbo ayé run.+
17 Màá gbé àwọn ará Mídíà dìde sí wọn,+Àwọn tí kò ka fàdákà sí nǹkan kan,Tí wúrà ò sì já mọ́ nǹkan kan lójú wọn.