-
Jeremáyà 51:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Asáréjíṣẹ́ kan sá lọ pàdé asáréjíṣẹ́ míì,
Òjíṣẹ́ kan sì lọ pàdé òjíṣẹ́ míì,
Láti ròyìn fún ọba Bábílónì pé wọ́n ti gba ìlú rẹ̀ láti apá ibi gbogbo,+
-