-
Àìsáyà 13:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Ará Arébíà kankan ò ní pàgọ́ síbẹ̀,
Olùṣọ́ àgùntàn kankan ò sì ní jẹ́ kí agbo ẹran rẹ̀ sinmi níbẹ̀.
-
-
Jeremáyà 51:43Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
43 Àwọn ìlú rẹ̀ ti di ohun àríbẹ̀rù, ilẹ̀ tí kò lómi àti aṣálẹ̀.
Ilẹ̀ tí ẹnì kankan kò ní gbé, tí èèyàn kankan kò sì ní gba ibẹ̀ kọjá.+
-