Àìsáyà 13:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Màá gbé àwọn ará Mídíà dìde sí wọn,+Àwọn tí kò ka fàdákà sí nǹkan kan,Tí wúrà ò sì já mọ́ nǹkan kan lójú wọn. 18 Ọfà wọn máa run àwọn ọ̀dọ́kùnrin túútúú;+Wọn ò ní káàánú èso ikùn,Wọn ò sì ní ṣàánú àwọn ọmọdé. Jeremáyà 50:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Torí náà, àwọn ọ̀dọ́kùnrin rẹ̀ á ṣubú ní àwọn gbàgede rẹ̀,+Gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀ á sì ṣègbé* ní ọjọ́ yẹn,” ni Jèhófà wí.
17 Màá gbé àwọn ará Mídíà dìde sí wọn,+Àwọn tí kò ka fàdákà sí nǹkan kan,Tí wúrà ò sì já mọ́ nǹkan kan lójú wọn. 18 Ọfà wọn máa run àwọn ọ̀dọ́kùnrin túútúú;+Wọn ò ní káàánú èso ikùn,Wọn ò sì ní ṣàánú àwọn ọmọdé.
30 Torí náà, àwọn ọ̀dọ́kùnrin rẹ̀ á ṣubú ní àwọn gbàgede rẹ̀,+Gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀ á sì ṣègbé* ní ọjọ́ yẹn,” ni Jèhófà wí.