-
Jeremáyà 50:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 “Ẹ sá kúrò nínú Bábílónì,
Ẹ jáde kúrò ní ilẹ̀ àwọn ará Kálídíà,+
Kí ẹ sì dà bí àgbò tó ń ṣíwájú agbo ẹran.
-
-
Sekaráyà 2:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 “Wá, Síónì! Sá àsálà, ìwọ tí ń gbé pẹ̀lú ọmọbìnrin Bábílónì.+
-