Ìfihàn 17:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Torí Ọlọ́run ti fi sí ọkàn wọn láti ṣe ohun tí òun fẹ́,+ àní láti ṣe ohun kan ṣoṣo tí wọ́n ń rò láti fún ẹranko náà ní ìjọba wọn,+ títí ìgbà tí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run máa ṣẹ délẹ̀délẹ̀.
17 Torí Ọlọ́run ti fi sí ọkàn wọn láti ṣe ohun tí òun fẹ́,+ àní láti ṣe ohun kan ṣoṣo tí wọ́n ń rò láti fún ẹranko náà ní ìjọba wọn,+ títí ìgbà tí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run máa ṣẹ délẹ̀délẹ̀.