Jeremáyà 50:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 “Wò ó! Mo dojú ìjà kọ ọ́,+ ìwọ aláìgbọràn,”+ ni Olúwa Ọba Aláṣẹ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí,“Nítorí ọjọ́ rẹ gbọ́dọ̀ dé, ní àkókò tí màá pè ọ́ wá jíhìn.
31 “Wò ó! Mo dojú ìjà kọ ọ́,+ ìwọ aláìgbọràn,”+ ni Olúwa Ọba Aláṣẹ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí,“Nítorí ọjọ́ rẹ gbọ́dọ̀ dé, ní àkókò tí màá pè ọ́ wá jíhìn.