Jeremáyà 25:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Torí náà, mo gba ife náà lọ́wọ́ Jèhófà, mo sì mú kí gbogbo orílẹ̀-èdè tí Jèhófà rán mi sí mu ún:+ Jeremáyà 25:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 àti gbogbo ọba àríwá, ti tòsí àti ti ọ̀nà jíjìn, ọ̀kan tẹ̀ lé èkejì àti gbogbo ìjọba yòókù tó wà lórí ilẹ̀ ayé, ọba Ṣéṣákì*+ pẹ̀lú á mu wáìnì náà lẹ́yìn wọn.
26 àti gbogbo ọba àríwá, ti tòsí àti ti ọ̀nà jíjìn, ọ̀kan tẹ̀ lé èkejì àti gbogbo ìjọba yòókù tó wà lórí ilẹ̀ ayé, ọba Ṣéṣákì*+ pẹ̀lú á mu wáìnì náà lẹ́yìn wọn.