-
Jeremáyà 49:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Báwo ló ṣe jẹ́ pé a kò tíì pa ìlú ìyìn tì,
Ìlú ayọ̀?
-
-
Dáníẹ́lì 4:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Ọba ń sọ pé: “Ṣebí Bábílónì Ńlá nìyí, tí mo fi agbára mi àti okun mi kọ́ fún ilé ọba àti fún ògo ọlá ńlá mi?”
-