Àìsáyà 13:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ìdí nìyẹn tí màá fi mú kí ọ̀run gbọ̀n rìrì,Ayé sì máa mì jìgìjìgì kúrò ní àyè rẹ̀+Nígbà tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun bá bínú gidigidi ní ọjọ́ ìbínú rẹ̀ tó ń jó bí iná.
13 Ìdí nìyẹn tí màá fi mú kí ọ̀run gbọ̀n rìrì,Ayé sì máa mì jìgìjìgì kúrò ní àyè rẹ̀+Nígbà tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun bá bínú gidigidi ní ọjọ́ ìbínú rẹ̀ tó ń jó bí iná.