Hábákúkù 2:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wò ó! Ṣé kì í ṣe Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ló ń mú kí àwọn èèyàn ṣiṣẹ́ kára fún ohun tó ṣì máa jóná,Tó sì ń mú kí àwọn orílẹ̀-èdè ṣe wàhálà lásán?+
13 Wò ó! Ṣé kì í ṣe Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ló ń mú kí àwọn èèyàn ṣiṣẹ́ kára fún ohun tó ṣì máa jóná,Tó sì ń mú kí àwọn orílẹ̀-èdè ṣe wàhálà lásán?+