Ìfihàn 18:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Áńgẹ́lì kan tó lágbára wá gbé òkúta kan tó dà bí ọlọ ńlá sókè, ó sì jù ú sínú òkun, ó ní: “Báyìí la ṣe máa yára ju Bábílónì ìlú ńlá náà sísàlẹ̀, a ò sì ní rí i mọ́ láé.+
21 Áńgẹ́lì kan tó lágbára wá gbé òkúta kan tó dà bí ọlọ ńlá sókè, ó sì jù ú sínú òkun, ó ní: “Báyìí la ṣe máa yára ju Bábílónì ìlú ńlá náà sísàlẹ̀, a ò sì ní rí i mọ́ láé.+