Jeremáyà 39:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ìgbà náà ni àwọn ará Kálídíà dáná sun ilé* ọba àti ilé àwọn èèyàn náà,+ wọ́n sì wó àwọn odi Jerúsálẹ́mù lulẹ̀.+
8 Ìgbà náà ni àwọn ará Kálídíà dáná sun ilé* ọba àti ilé àwọn èèyàn náà,+ wọ́n sì wó àwọn odi Jerúsálẹ́mù lulẹ̀.+