-
Jeremáyà 39:9, 10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Nebusarádánì+ olórí ẹ̀ṣọ́ kó àwọn tó ṣẹ́ kù lára àwọn èèyàn tó wà ní ìlú náà lọ sí ìgbèkùn ní Bábílónì àti àwọn tó sá wá sọ́dọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ẹnikẹ́ni tí ó ṣẹ́ kù.
10 Àmọ́ Nebusarádánì olórí ẹ̀ṣọ́ fi lára àwọn aláìní sílẹ̀ ní ilẹ̀ Júdà, àwọn tí kò ní nǹkan kan. Lọ́jọ́ yẹn, ó tún fún wọn ní ọgbà àjàrà àti oko láti máa ṣiṣẹ́.*+
-