-
1 Àwọn Ọba 7:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Wọ́n gbé Òkun náà ka orí akọ màlúù méjìlá (12),+ mẹ́ta dojú kọ àríwá, mẹ́ta dojú kọ ìwọ̀ oòrùn, mẹ́ta dojú kọ gúúsù, mẹ́ta sì dojú kọ ìlà oòrùn; Òkun náà wà lórí wọn, gbogbo wọn sì kọ̀dí sí abẹ́ Òkun náà.
-