Jeremáyà 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà wá na ọwọ́ rẹ̀, ó sì fi kan ẹnu mi.+ Jèhófà sì sọ fún mi pé: “Mo ti fi ọ̀rọ̀ mi sí ẹnu rẹ.+