-
Jeremáyà 1:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ni Jèhófà bá sọ fún mi pé:
“Ìyọnu máa tú jáde láti àríwá
Sára gbogbo àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà.+
-
-
Jeremáyà 10:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Fetí sílẹ̀! Ìròyìn kan ń bọ̀!
-