Àìsáyà 3:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jèhófà sọ pé: “Torí pé àwọn ọmọbìnrin Síónì ń gbéra ga,Tí wọ́n ń gbé orí wọn sókè* bí wọ́n ṣe ń rìn,Tí wọ́n ń sejú, tí wọ́n sì ń ṣakọ lọ,Wọ́n ń mú kí ẹ̀gbà ẹsẹ̀ wọn máa dún woroworo,
16 Jèhófà sọ pé: “Torí pé àwọn ọmọbìnrin Síónì ń gbéra ga,Tí wọ́n ń gbé orí wọn sókè* bí wọ́n ṣe ń rìn,Tí wọ́n ń sejú, tí wọ́n sì ń ṣakọ lọ,Wọ́n ń mú kí ẹ̀gbà ẹsẹ̀ wọn máa dún woroworo,