Àìsáyà 24:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ayọ̀ ìlù tanboríìnì ti dáwọ́ dúró;Ariwo àwọn tó ń ṣe àríyá ti dópin;Ìró ayọ̀ háàpù ti dáwọ́ dúró.+ Jeremáyà 25:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Màá fòpin sí ìró ayọ̀ àti ìró ìdùnnú láàárín wọn,+ màá sì tún fòpin sí ohùn ọkọ ìyàwó àti ohùn ìyàwó,+ ìró ọlọ àti ìmọ́lẹ̀ fìtílà.
10 Màá fòpin sí ìró ayọ̀ àti ìró ìdùnnú láàárín wọn,+ màá sì tún fòpin sí ohùn ọkọ ìyàwó àti ohùn ìyàwó,+ ìró ọlọ àti ìmọ́lẹ̀ fìtílà.