Àìsáyà 8:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà sọ fún mi pé: “Mú wàláà+ ńlá kan, kí o sì fi kálàmù lásán,* kọ ‘Maheri-ṣalali-háṣí-básì’* sára rẹ̀.
8 Jèhófà sọ fún mi pé: “Mú wàláà+ ńlá kan, kí o sì fi kálàmù lásán,* kọ ‘Maheri-ṣalali-háṣí-básì’* sára rẹ̀.