-
Jeremáyà 23:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 “Nítorí náà, ọ̀nà wọn á di ibi tó ń yọ̀, tó sì ṣókùnkùn;+
A ó tì wọ́n, wọ́n á sì ṣubú.
Torí pé màá mú àjálù bá wọn
Ní ọdún ìbẹ̀wò,” ni Jèhófà wí.
-