-
Jeremáyà 30:12, 13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Nítorí ohun tí Jèhófà sọ nìyí:
“Kò sí ìwòsàn fún àárẹ̀ tó ń ṣe ọ́.+
Ọgbẹ́ rẹ kò ṣeé wò sàn.
13 Kò sí ẹni tó máa gba ẹjọ́ rẹ rò,
Egbò rẹ kò ṣeé wò sàn.
Kò sí ìwòsàn fún ọ.
-