-
Jeremáyà 12:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Kódà, àwọn arákùnrin rẹ, ìyẹn àwọn ará ilé bàbá rẹ,
Ti hùwà àìṣòótọ́ sí ọ.+
Wọ́n ti kígbe lé ọ lórí.
Má gbà wọ́n gbọ́,
Kódà tí wọ́n bá tiẹ̀ sọ àwọn ohun rere fún ọ.
-
-
Míkà 7:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Gbogbo wọn lúgọ kí wọ́n lè ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀.+
Kálukú wọn ń fi àwọ̀n dọdẹ arákùnrin rẹ̀.
-
-
Míkà 7:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Má ṣe gbára lé ẹnì kejì rẹ,
Má sì gbẹ́kẹ̀ lé ọ̀rẹ́ rẹ tímọ́tímọ́.+
Máa ṣọ́ ohun tí wàá sọ fún ẹni tó ń sùn sí àyà rẹ.
-