ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 6:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Kò sí ẹni tó lágídí tó wọn láyé,+

      Wọ́n ń rìn káàkiri bí abanijẹ́.+

      Wọ́n dà bíi bàbà àti irin;

      Ìwà ìbàjẹ́ kún ọwọ́ gbogbo wọn.

  • Ìsíkíẹ́lì 22:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Inú rẹ ni àwọn abanijẹ́ tó pinnu láti ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀ wà.+ Wọ́n ń jẹ ẹbọ lórí àwọn òkè nínú rẹ, wọ́n sì ń hùwà àìnítìjú láàárín rẹ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́