-
Jeremáyà 5:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 “Ǹjẹ́ kò yẹ kí n pè wọ́n wá jíhìn nítorí nǹkan wọ̀nyí?” ni Jèhófà wí.
“Ǹjẹ́ kò yẹ kí n* gbẹ̀san lára orílẹ̀-èdè tó ṣe irú èyí?
-