Jeremáyà 10:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Fetí sílẹ̀! Ìròyìn kan ń bọ̀! Ariwo rúkèrúdò láti ilẹ̀ àríwá,+Láti sọ àwọn ìlú Júdà di ahoro, ibùgbé àwọn ajáko.*+
22 Fetí sílẹ̀! Ìròyìn kan ń bọ̀! Ariwo rúkèrúdò láti ilẹ̀ àríwá,+Láti sọ àwọn ìlú Júdà di ahoro, ibùgbé àwọn ajáko.*+